Go to full page →

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Pẹ̀lú Ojú Tí ó Ti Fọ́ IIO 161

Ọpọlọpọ àwọn tí ó kópa láti fi ìsinmi ọjọ kìn-ín-ní ọsẹ múlẹ ṣugbọn ni wọn foju si àyọrísí ìgbésẹ wọnyìí. Wọn kò sì mọ, ń ṣe ni wọn ńgbógun ti òmìnira ẹsìn. Bẹẹ sì ni ọpọlọpọ ni òye ọjọ ìsinmi, ọjọ kèéje ti ìnu Bíbélì kò ye àti ìpìlẹ èké èyí tí ọjọ kìn-ín-ní ọsẹ dúró lé.-Testimonies, Vol. 5, p. 711. IIO 161.3