Go to full page →

Àpẹẹrẹ Tí ó Yè IIO 171

Bóyá tálákà opó’bìnrin tí ó sọ owó idẹ wéwé méjì sínú àpótì ìsura Olúwa fi taratara mo ìtumò ohun tí ó se è nì nítorí àpeere ohun tí ó se è nì ó tí fi owó tó òpòlopò okàn ní orílè-èdè gbogbo jákèjádò àgbáyé. Ohun tí ó se èyí ní ó tí mú kí òpòlopò ó mú ore won wá sínú ìsura Olúwa yálà àwon tálákà tàbí olórò. Èyí sì tí mú kí isé Olúwa ó ní ìtèsíwájú yálà nípa kíkéde ìhìnrere ní tàbí kíkó ilé ìwòsàn ní tàbí bíbó àwon aláìní tàbí fífí aso fún àwon tí wón wà ní ìhòòho. Òpòlopò ní ó sì tí dí alábùkún fún nípa ìwà aláìní ìmo tara ení nìkan èyí tí ó tí hù yìí.- Testimonies, Vol. 6, p. 310. IIO 171.2