Go to full page →

Kínni Ìwo Ń Se Níhìnyìí? IIO 182

Òpò ènìyàn ní ó gbékèlé ìgbádun àìlópin tí wón ń rí gbà láti òdò àwon tí ó jé olótìtó sí won, fún ìdí èléyì, Sátánì sì wá ń lo àǹfàaní yìí láti ba èró Olórjun jé èyí tí Olórun fé se nípa ìgboran. Ó jẹ́ kí òpòlopò ó gbàgbé àfojúsùn won, èyí tí isé mímó tí a gbé lé won lọ́wọ́ tí ó sì mú won ní ìtélórùn pèlú afé ayé. Ó mú kí wọn ó jókò tẹtẹrẹ pèlú ìtelórùn pèlú orò ayé ní mímú won kúrò ní ìbí tí jé agbára fún ohun rere. Ó dá ìrèwèsì sí okàn àwon elòmíràn kí wón lè sá kúrò lénu isé won nítorí àtakò tàbí ìpónjú. Sùgbón irú àwon wònyí ni orùn ń wò pèlú ojú ìkáanú. Sí gbogbo ọmọ Olórun tí òtá ti pa lénu mó, ìbéèrè tí á ò bá béèrè lówó won ni, “Kínni ìwo ń se níhìn yìí?” Mo gbé kalè láti kéde ìhìnrere, kí e sì pèsè àwon ènìyàn sílè fún ojó Olúwa. Kínni ìdí tí ó se wà níbí? Tani ó rán ọ?-Prophets and Kings, pp. 171, 172. IIO 182.1

Bí ó se rí fún enìkòòkan náà ló rí fún ìdílé, ìbéèrè tí a ò bá bi wón ní wípé, “Kínni è ń se níhìn yìí?” Òpò ìdílé tí ó mọ òtító òrò Olórun dáadáa ní ó ye kí wón lo agbára won láti máa lọ káàkiri láti kéde òtító náà fún gbogbo àwon tí ó nílò rè.-Prophets and Kings, p. 172. IIO 182.2