Go to full page →

ORÍ KẸTÀDÍNLÓGÚN Ìràńlọ́wọ́ ọ Ti Àwọn Onígbàgbọ́ IIO 186

Títọ Ipa Ọ̀run Lẹ́hìn IIO 186

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ni wọ́n rò wípé anfààní ńlá ni yóò jẹ́ fún wọn láti ṣe àbẹ̀wò sí ibi ìgbé ayé Jésù nígbà tí Ó wà lááyé, láti rìn ní ọ̀nà tí ó gbà, àti láti tọ ipa ọ̀nà tí ó nífẹ̀ẹ́ láti kọ́. (The Desire of Ages, pp. 86, 87). IIO 186.1