Go to full page →

Yíyan Àsíá Ìdílé IIO 209

Mo rí Sátánì tí ó ń fi àmìn àsíá rẹ̀ sórí àwọn ìdílé tí wọn sọ wí pé wọn jẹ́ ti Ọlọ́run, ṣùgbọ́n àwọn tí wọ́n ń rìn nínú ìmọ́lẹ̀ yóò mọ̀ àmìn ìyàtọ̀ tí ó wà láàárín àsíá dúdú tí àwọn ọ̀tá àti ti àsíá Kírísítì ti àgbékalẹ̀ àsíá Kírísítì tí ó fi ẹ̀jẹ̀ Rẹ̀ ṣe.-Testimonies, Vol. 4, p. 200. IIO 209.2