Go to full page →

Pàtàkì Akitiyan Lórí Ìbẹ̀wò IIO 219

Nígbà tí a bá ṣe àgbékalẹ̀ òtítọ́ yìí ni ìpéjọpọ̀ tí ó tóbi, ó yẹ kí mọ̀ wí pé àwọn ènìyàn yóò fẹ́ láti bèèrè ìbéèrè, ó ṣe pàtàkì láti máa bẹ àwọn wọ̀nyìí wò fúnra wa. Ó yẹ kí a kọ́ àwọn tí ó bá nífẹ́ láti bèèrè ìbéérè lórí òtítọ́ yìí lẹ́kọ̀ọ́ gidigidi nínú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. Ó yẹ kí ẹnìkan ó ràn wọ́n lọwọ láti dúró lórí ìpìlẹ̀ tí ó le. Ní àkoko tí ìmọ̀ wọn kò tíì kún tó nínú ìrírí wọn nínú ẹ̀sìn yìí, ó ṣe pàtàkì làti yan àwọn tí ó ní ìmọ̀ Bíbélì tí wọ́n lè ràn wọ́n lọ́wọ́ láti lèè ní ìmọ̀ kíkún nínú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.-Testimonies, Vol. 9, p.111. IIO 219.5

Ìbá dára láti máa fí òtítọ́ yìí hàn wọ́n tí a bá jẹ́ kí wọ́n pàdánù ànfààní iyebíye yìí nípa ṣíṣe aláì bẹ̀ wọ́n wò nítorí yóò niran láti lèè tún pàrọwà fún ọkàn wọn mọ́.-Testimonies, Vol. 2, p. 118. IIO 220.1