Go to full page →

Pèlú Ìpinnu IIO 229

Àwon tí ó bá wà níbi isé Olórun gbodò ní èmí ìpinnu àti ìdárayá láti se isé ìjèrè okàn. E rántí wípé àwon kan yóò sègbé àyàfi tí àwa gégébí ohun èlò Olórun bá sisé pèlú ìpinnu tí kò ní bàkù tàbí rèwèsì.-Testimonies, Vol 6, p. 418. IIO 229.4

Ó ti fún wa ní isé ń lá láti se, e jé kí a se é pèlú ìsedéédé àti ìpinnu. E jé kí a fihàn nínú ayé wa ohun tí òtító ti se fún wa.-Testimonies, Vol. 6, p. 418. IIO 229.5