Go to full page →

Ìgbáradì IIO 243

Jé olótító akoni, láti fi ìyìn eni tí ó pè ó kúrò nínú òkùnkùn sínú ìmólè ń lá a Rè.-Review and Herald, Jan. 24, 1893. IIO 243.5

Àwon òsìsé Olórun gbodò gbáradì láti yara sisé bí ìpèsè sílè ẹ Rẹ̀ bá se lànà. Ìdènà bíńtín ni ipasè won má fún Sàtánì ní ààyè láti borí won.-Patriarchs and Prophets, p. 423. IIO 244.1

Àwon ènìyàn Rè tí ó ń pa òfin mó gbodò dúró nígbà gbogbo láti sisé.-Testimonies, Vol. 8, p. 247. IIO 244.2

Àwon tí ó ń sojú Olórun nítòótó ń sisé fún rere àwon elòmíràn. Won yóò nínú ìmútèsíwájú isé Olórun ní ilé àti lóko. À ń rí won, béè là ń gbó won, a sì ń rí ipa won, ní ìpéjopò àdúrà. Won a máa gbìyànjú láti sojú àlùfáà. Won kìí wá ti ara won tàbi gba oríyìn fún isé rere won, sùgbón wón sisé pèlú ìrèlè àti òtító, nígbà tí wón bá sisé ń lá tàbí kékeré nítorí Kristi ti se òpòlopò fún won.-Review and Herald, Sept. 6, 1881. IIO 244.3