Go to full page →

Àṣeyọrí Tí ó Ní Òṣùwọ̀n IIO 262

Nígbà tí Olórun bá lànà fún àṣeyorí iṣé kan, Ó má a ń ṣèlérí àṣeyorí, àwon tí a yàn láti ṣe isé ń lá náà gbodò sa ipa a won láti rí àbáyorí ìlérí náà. Tí a bá fi ìtara àti ìforítì se isé náà, àseyorí ni òpin yóò jé (Prophets and Kings, p.263). IIO 262.2