Go to full page →

Ìdílé Ìdíyelé IIO 266

À ń won iye isé tí a se fún Olórun nípa irú èmí tí a fi se é, kìí se bí isé ti pé tó.-Testimonies, Vol. 9, p. 74. IIO 266.4

Àṣeyọrí i wọn nínú ẹ̀mí faralé ìtẹ̀síwájú wọn tàbí ìdàgbàsókè wọn nínú èbùn tí a fi fún wọn. A yóò fi èrè fún ọjọ́ ọ̀la nípa ìfìdímúlẹ̀ àti ìtara tí wọn fi sin Ọlọ́run.- Review and Herald, Mar. 1, 1887. IIO 266.5

Oluwa ní iṣẹ́ ń lá láti ṣe yóò sì fún àwọn ènìyàn ní ojó iwájú, èyí ni àwọn tí ó gbàgbọ́ jùlọ, tí ó ṣetán láti ṣiṣẹ́ nínú ayé tí a wà yìí.- Christ Object Lessons, P.330. IIO 266.6

Àwọn tí ó wọ inú ọgbà àjàrà ní àkókò tí ó kẹ́yìn pátápátá dúpé fún ànfààní láti ṣiṣẹ́. Ọ̀ràn a wọn kún fún ọpẹ́ sí ẹni tí ó gbà wọ́n nígbà tí ó san owó òde di ọjọ́ kan fún wọn èyí sì yà wọ́n lẹ́nu. Wọ́n mọ̀ pé àwọn yóò ṣiṣẹ́ tí ó yẹ fún owó iṣẹ́ tí ó san fún wọn, irú ọrẹ yìí mú wọn kún fún ayọ̀, tí wọn ó sì gbàgbé ore ẹni tí ó gbà wọ́n ṣíṣẹ́. IIO 266.7

Bí ó ti rí pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ni èyí, láì mọ̀ pé àì pé, tí wọ inú ọgbà àjàrà Olúwa ní àkókò tí ó kẹ́yìn pátápátá, àsìkò ìsin rẹ̀ jẹ́ kékeré, o sì rò pé òun kò yẹ fún èrè, ṣùgbọ́n ó kún fún ayọ̀ pé Olọrun ti gba ohun. Ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ọkàn ìrẹ̀lẹ̀, ẹ̀mí tí ó gbàgbọ́, irú ọkàn yìí ni Ọlọ́run fẹ́ fún ní ẹ̀yẹ.- Christ’s Object Lessons, pp.397,398. IIO 267.1