Go to full page →

Dídi Aláìníbò Nípa Ìmọ̀tara- Ẹni- Nìkan. IIO 40

A ti fi hàn mí ìdí tí àwọn ènìyàn Ọlọ́run kò fi fi ọkàn sí n ǹkan ti ẹ̀mí tí wọn kò sì ní ìgbàgbọ́ mọ́,Ìdí ni pé wọ́n di aláìníbò pẹ̀lú ìmọtara ẹni nìkan....Kì í ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpàdé è rẹ ni Ọlọ́run tẹ́wọ́gbà.Kì í ṣe àì mọye àwọn àdúrà, ṣùgbọ́n ṣíṣe ohun tí ó tọ̀nà, àti ní àsìkò tí ó tọ́.-Testimonies,vol.2, p.36. IIO 40.3