Go to full page →

Àgara Ń dá àwọn Tí wọ́n Ń ru Ẹrù IIO 45

Nítorí pé, àwọn mìíràn kò ní gbé àwọn ìṣòro tí wọ́n lè gbé, tàbí ṣiṣẹ́ tí wọ́n lè ṣe,iṣẹ́ yìí tóbi jù fún àwọn díẹ̀ tí wọ́n ń ṣe e. Wọ́n rí i pé wọ́n lo agbára wọn jù, bẹ́ẹ̀ ni wọn sì ti yára darúgbó.-Testimonies,vol.2, p.645. IIO 45.3