Go to full page →

Àwọn Mìíràn Yóò Tọ Ipa Ìsọtẹ́lẹ̀ IIO 46

Ọlọ́run ní àwọn ènìyàn lórí ilẹ̀ ayé tí ó jẹ́ pé nínú ìgbàgbọ́ àti ìrètí mímọ́ ń tọ ipa asọtẹlẹ, wọ́n sì ń wá láti ya ọkàn an wọn sí mímọ́ nípa gbígbọ́ràn sí òtítọ́, kí wọn má baà rí wọn láì ní aṣọ ìgbeyàwó nígbà tí Krístì yóò bá farahàn.-Testimonies, vol.4,p.307. IIO 46.2