Go to full page →

Ayé Ti Dàbí Ilé N ǹkan Ọ̀sìn IIO 53

Ènìyàn nínú ìfọ́jú u wọn ń yangàn ti ìtẹ̀síwájú ìyanu àti ìla lọ́yẹ̀; ṣùgbọ́n ẹni tí ó ń wò láti ọ̀run ń rí ayé tí ó kún fún ìjẹkújẹ àti ìwà ipá. Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àfẹ́fẹ́ tí ó yí ayé e wa ká ti dàbí afẹ́fẹ́ tí ó wà ní àyíká ilé n ǹkan ọ̀sìn.- Testimonies, vol.6.pp. 10,11. IIO 53.1