Go to full page →

Ọ̀rọ̀ Àmì Onígbàgbọ́ IIO 106

Àwọn ọ̀rọ̀ àmì mẹ́ta ni ó wà nínú ayé onígbàgbọ́, tí a ní láti kíyèsí tí a kò bá fẹ́ kí èṣù kó borí i wa; àwọn wọ̀nyí ni ṣọ́ra, gbàdúrà,ṣiṣẹ́.- Testimonies, vol.2, p.283. IIO 106.3

Gbogbo ọkàn tí ó bá ti jẹ́wọ́ Krístì ti fi ara a wọn jẹ́jẹ́ láti jẹ́ ohun gbogbo tí ó ṣe é ṣe Fún-un láti jẹ́ òṣìṣẹ́ ẹ ti ẹ̀mí, láti ṣaápọn, ní ìtara, àti láti lágbára nínú iṣẹ́ Olúwa a rẹ̀. Ọlọrun ń retí kí ẹnìkọ̀ọ̀kan ṣe iṣẹ́ ẹ rẹ̀, jẹ́ kí eléyìí jẹ́ ọ̀rọ̀ àmì jákè jádò àwọn ẹgbẹ́ ẹ ti àtẹ̀lé e RẸ̀.- Testimonies, vol.5, p.460. IIO 106.4