Go to full page →

Ìlérí Tó Tunilára IIO 214

Ọlọ́run yóò rántí àwọn tí wọ́n péjọ pọ̀ láti ṣe àṣàrò lórí Orúkọ Rẹ̀, yóò si pa wọ́n mọ́ kúrò nínú iná ńlá náà. Wọn ó sì jẹ́ ohun ọ̀ṣọ́ iyebíye ní iwájú Rè.-Testimonies, Vol. 4, p. 107. IIO 214.2