Go to full page →

Ìwà Pèlé IIO 241

Èmí tí ó wà ní pèlé nínú ìrusókè tàbí ìmúnibínú yóò sòrò dáadáa nínú òtító ju gbogbo àríyànjiyàn lo bí ó ti wù kí ìmúnibínú náà le tó.-The Desire of Ages, p. 353. IIO 241.1

Bí ìrì àti òjò se ń rò sórí koríko tí ó ń kú lo, béè ni kí òrò ìtósónà se má jáde nígbà tí a bá ń bá àwon ènìyàn sòrò láti ḿu won bó s’ágbo nínú èsè won, ìpinnu Olórun ni láti kókó gba okàn wa. Ó gbudò so òtító nínú ìfé, kí a gbàgbó nínú eni tí ó ń fún ni l’ágbára láti yí ayé eniyan padà. Èmí Mímó yóò fowóba eni tí a bá sòrò nínú ìfé.-The Ministry of Healing, p. 157. IIO 241.2

Níní èmí pèlé nígbà tí a bá fa okàn wa s’ágbo lè gba okàn tí ó sìnà, tí yóò sì bo òpòlopò èsè. Ìfihàn Olórun nínú ìwà rè yóò ní agbára ìyípadà lórí gbogbo àwon tí ó bá bá pàdé, jé kí Olorun kó farahàn nínú ayé re lójoojúmó, yóò sì t’ara rè fi agbára òrò Rè hàn nípasè rè ní ònà tí ó yàtò, ìwà pèlé, ìwà ìyínilókànpadà síbè ó ní ipa gidi láti tún okàn rò nínú ewà Olúwa wa.-Thought from the Mount of Blessssing, p. 129. IIO 241.3