Go to full page →

Ìṣòtítọ́— Àìṣèrú —Aápọn IIO 242

Nígbà tí a bá gbé isé fún ènìyàn, a kìí bèèrè bóyá ó ní èbùn òrò síso tàbí ó lówó ṣùgbón bóyá ó jẹ́ olóóótọ́,olódodo àti ẹni tí ó lè ṣiṣẹ́; ohunkóhun tí ó lè jé àṣeyọrí i rẹ̀, láìní àwon àmúye yìí, kò ye rárá fún ipòkípò tí ó nílò ìgbáralé Kankan.-Tesimonies, Vol. 4, p. 413. IIO 242.2