Go to full page →

Ọ̀pọlọpọ̀ Ń dúró Fún Ìgbà Ìtura IIO 255

Òpòlopò tí ó ye kí won fi ogbón má lo ànfààní tí ó yojú sí won, ni ó ń dúró fún àsìkò òtò fún èmí-mímó, nígbà tí agbára won láti tan ìmólè sí elòmíràn yóò pò. Won fi isé tí ó ye kì won ó se sílè báyìí ohun ànfààní tí ó yojú síwon, wón sì jé kí ìmólè won kí ó rinlè, nígbà tí wón dúró de ìgbà tí won kò ní sapá kankan nípasè ara won láti gba ìbùkún òrò tí won kò fi yípadà àti ye fún isé ìsìn.-The Acts of Apostles, p. 54. IIO 255.2