Go to full page →

Arọ́pọ̀ o Krístì IIO 255

Èmí-Mímó jé asojú Kristi, sùgbón tibe kúrò ohun tíí se ti ènìyàn, ó sì dáwà. Nítorí èyí ni ó se lo sódò Baba, tí ó sì rán èmí-mímó gégé bí asojú rè nínú ayé. Kò si eni tí ó lè rí ànfààní rè nítorí ibi tí ó wà tàbí ìbásepò rè pèlú Kristi. Nípasè èmí-mímó, gbogbo ènìyàn ni ó lè rí Jésú fún ìdí èyí, yóò sún mó wa jù bì a kò bá gbà á sókè lo sórun.-The Desire of Ages, p. 699. IIO 255.3