Go to full page →

Gbígbani níyànjú Ẹ̀mí Ajíhìnrere IIO 65

ọn olùkọ́ àti àwọn ọmọ ilé-ìwé nínú àwọn ilé-ìwe e wa nílò ìfọwọ́kàn ti ọ̀run.Ọlọ́run le è ṣe jù bẹ́ ẹ̀ lọ fún wọn ju èyí tí Ó ti ṣe, nítorí pé látẹ̀yìn wá ọ̀nà a Rẹ̀ ni a ti pààlà fún. Tí a bá gba ẹ̀mí ajíhìnrere níyànjú, kódà tí yóò bá gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ díẹ̀ ìwé ètò ti ìkẹ́kọ̀ọ́ déédé, ọ̀pọ̀ ìbùkún ọ̀run ní àó rí gbà, tí a bá ní ọ̀pọ̀ ìgbàgbọ́ àti ìtara, àti ọ̀pọ̀ ohun tí Ọlọ́run yóò ṣe.- Counsels to Teachers, p.546. IIO 65.4