Go to full page →

Ṣíṣe Ìdásílẹ̀ Ìbi ìṣúra IIO 154

Ní ibi gbogbo tí ó ṣe pàtàkì a gbọdọ̀ ní ibi ìṣúra fún àwọn ìwé àtẹ̀jáde. Àwọn díẹ̀ tí wọ́n mọ rírì òtítọ́ gbọdọ̀ fi ìfẹ́ ẹ wọn hàn láti fi àwọn ìwé yìí sí ọwọ́ àwọn tí wọn yóò kà á.- Testimonies, vol.1, p.473. IIO 154.2