Go to full page →

Ìgbésẹ̀ Àkọ́kọ́ Nínú u ṣíṣe Ètò Ìjọ IIO 73

Níbi ìgbọ́wọ́ lé lórí àwọn méjìlá ni ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ ti wáyé nínú ìjọ kíkójọ pé lẹ́yìn tí Jésù bá gòkè lọ sí ọ̀run wọn yóò lè tẹ̀síwájú nínú iṣẹ́ ẹ Rẹ̀ ní ayé.- The Acts of The Apostles, p.18. IIO 73.4