Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents
ISE ISIN ONIGBAGBO - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    ORÍ — KEJÌ ÌPÈ SI ÀWỌN Ọ̀DỌ́

    Yíyàn Láti Ọ̀run

    Olúwa ti yan àwọn ọ̀dọ́ láti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ ọ rẹ̀.—Testimonies, vol. 7, p. 64.IIO 30.1

    Pẹ̀lú àwọn jagun jagun àwọn òṣìṣẹ́ bí àwọn ọ̀dọ́, tí a kọ́ lọ́nà tòótọ́, tí a fún ní agbára, báwo ni iṣẹ́ ìránṣẹ́ ti Olùgbàlà tí a kàn mọ́ àgbélébùú, tí ó jíǹde àti ìpadàbọ̀ Olùgbàlà yóò ṣe lọ sí gbogbo ayé.—Education, p. 271.IIO 30.2

    À ǹ rì ọmọ ogun ti ọ̀dọ́ lónìí tí ó lè ṣe púpọ̀ tí a bá darí i wọn dáadáa tí a sì ń gbà wọ́n níyànjú. A fẹ́ kí àwọn ọmọ wa gba òtítọ́ gbọ́. A fẹ́ kí Ọlọ́run bùkún wọn, a fẹ́ kí wọn kópa nínú ètò tí a gbé kalẹ̀ dáadáa fún ìràn lọ́wọ́ ọ̀dọ́ míràn. Kí a kọ́ wọn dáadáa kí wọn lè jẹ́ aṣojú ti òtítọ́, fún wọn ní ìdí ti ìrètí tí ó wà ní ìkáwọ́ wọn, kí wọn sì bu ọlá fún Ọlọ́run nínú ẹ̀ka kẹ́ka tí wọ́n yẹ lati ṣiṣẹ.—General Conference Bulletin, vol. 5,no. 2, p. 24 (Jan. 29, 30, 1893).IIO 30.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents