Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents
ISE ISIN ONIGBAGBO - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    A Ti Fa Ọwọ́ Ìdálẹ́kun Ẹ̀mí Ọlọ́run sẹ́yìn

    Ìdálẹ́kun Ẹ̀mí Ọlọ́run ni a ti fa ọwọ́ ọ rẹ̀ sẹ́yìn nísinsinyìí, ìjì líle, ìjì, ẹ̀fúùfù líle, iná àti ẹ̀jẹ̀, àwọn ìjàm̀bá nípa òkun àti ilẹ̀, ń tẹ̀lé ara wọn ní ṣíṣẹ̀ n tẹ̀lé, ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ń wá láti ṣ’àlàyé gbogbo n nkan wọnyii. Àwọn àmìn wọ̀nyìí tó ń ṣẹ̀ ní àyíká a wa, ń fi sísúnmọ́ tòsí ọmọ ènìyàn han, ni a kà sí àmìn ohun mìíràn yàtọ̀ fún ohun tí ó jẹ́.Ènìyàn kò lè mọ áńgẹ́lì olùṣọ tí ó ń so orígun mẹ́rẹ̀rín ayé láti má jẹ̀ ẹ́ kí ó fọ́ títí tí àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run yóò fi fi èdìdì dì í; Ṣùgbọ́n nígbà tí Ọlọ́run yóò pàṣẹ fún àwọn àńgẹ́lì i Rẹ̀ láti ti orígun yì ì. Ìṣẹ̀lẹ̀ ìjà tí a kò le è ṣàlàyé yóò ṣẹlẹ̀.—Testimonies, vol. 6, p. 408.IIO 52.2

    Àsìkò tí à ń gbé yì í lọ́wọ̀ ó sì ṣe pàtàkì. À ń gbá ẹ̀mí Ọlọ́run díẹ̀ díẹ̀ kúrò nínú ayè. Àjàkálẹ̀ àrùn àti ìdájọ́ tilẹ̀ ti ń bọ̀ sórí àwọn tí ó gan oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run. Jàm̀bá nípa ti ti ilẹ̀ àti òkun, àìní fọ̀kàn balẹ̀ ipò ti ẹgbẹ́, ìro ogun,jẹ amin isọtẹlẹ. Wọ́n ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ sísúnmọ́ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ń lá. Àwọn aṣojú u ti èṣù ń kó ara wọn jọ pọ̀ sógun, wọ́n ṣọ̀kan. Wọ́n ń ró wọn lágbára fún ìdàrú dàpọ̀ ìkẹhìn. Àyípadà ń lá láìpẹ́ yóò ṣẹlẹ̀ nínú ayé e wa, ìjáde lọ yóò sì jẹ́ kíà kíà.—Testimonies, vol. 9, p. 11.IIO 52.3

    Àsìkò náà súnmọ́ etílé nígbà tí ìkáàánú tàbí ìbànújẹ́ yóò wà nínú ayé tí kò sí ìkunra tí yóò le è wó sàn. Ẹ̀mí Olúwa ni a ti mú kúrò. Ìjàm̀bá lórí omi àti lórí ilẹ̀ ń tẹ̀lé ra ní ṣíṣẹ̀ n tẹ̀lé.Nígbàkúùgbà ni à ń gbọ́ nípa ilẹ̀ ríri tàbí ẹ̀fúùfù ń lá, ijamba nípa iná àti ìkún omi, pẹ̀lú ṣísòfò ẹ̀mí àti dúkìá! Ó hàn gbangba pé àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ yì í jẹ́ àyọrísí burúkú tí ìdàrúdàpọ̀, àti àílétò nínú àwọn agbára ìsẹ̀dá ṣokúnfá a rẹ́,èyí tí ó kọjá agbára ènìyàn; ṣùgbọ́n nínú u wọn, a le è kà nípa èrò Ọlọ́run.Wọ́n wà lára àwọn aṣojú nípa èyí tí yóò wá láti ta ọkùnrin àti obìnrin jí láti mọ̀ nípa ewu tí yóò wu wọ́n.—Prophets and Kings, p. 277.IIO 52.4

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents