Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents
ISE ISIN ONIGBAGBO - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ṣíṣe Ìmúlò Ìkọ́ni

    Ẹni mélòó ni òṣìṣẹ́ Ọlọ́run tí ó wúlò tí a sì bu ọlá fún nínú iṣẹ́ Ọlọ́run ni ó ti gba ẹ̀kọ́ láarin àwọn iṣẹ́ tí ó rẹlẹ̀ tí ó kọjá ipò ìrẹ̀lẹ̀ nínú ayé! Mósè jẹ́ alákóso tí a fojú sùn ní ilẹ̀ Éjíbítì, ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò lè mú u lọ sí àgbàlá ọba láti ṣe iṣẹ́ tí ó yàn án.Kìkì ìgbà tí ó wà níbẹ̀ fún ogójì ọdún tí ó jẹ́ olùṣọ́ àgùtàn òdodo ni a rán an láti jẹ́ olùgbàlà àwọn ènìyàn an rẹ̀. Gídíónì ni a mú kúrò níbi ìpakà láti jẹ́ ohun èlò ní ọwọ́ Ọlọ́run fún ìgbàlà àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì. A pè Èlíṣà láti ibi ìtulẹ̀ ẹ rẹ̀ láti gba ìpè Ọlọ́run.Àmósì jẹ́ olùtọ́jú oko àti àgbẹ̀, nígbà tí Ọlọ́run fún un ní iṣẹ́ ìránṣẹ́ láti polongo. Gbogbo àwọn tí ó jẹ́ alábá-ṣiṣẹ́-pọ̀ pẹ̀lú u Krístì ni wọn má a nípìn ín nínú ohun tí ó nira,.-Gospel workers, pp.332,333.IIO 60.2

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents