Loading...
Larger font
Smaller font
Copy
Print
Contents
ISE ISIN ONIGBAGBO - Contents
  • Results
  • Related
  • Featured
No results found for: "".
  • Weighted Relevancy
  • Content Sequence
  • Relevancy
  • Earliest First
  • Latest First
    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents

    Ìlànà Ìkọ́ni Fún Ajíhìnrere

    Ọ̀pọ̀ ni ìbá fẹ́ láti ṣiṣẹ́ tí ó bá jẹ́ pé wọ́n kọ́ wọn bí wọn yóò ṣe bẹ̀rẹ̀. Wọ́n ní láti fún wọn ní ẹ̀kọ́ àti ìgbani níyànjú. Olúkúlùkù ìjọ gbọdọ̀ jẹ́ ilé-ìwé tí a ti ń kọ́ àwọn òṣìṣẹ́ onígbàgbọ́. Ọmọ ìjọ ni a gbọdọ̀ kọ́ bí wọ́n ṣe ń ka Bíbélì, bí wọ́n ṣe le è lò ó láti kọ́ ilé- ẹ̀kọ́ ọjọ́ ìsinmi, báwo ni wọ́n ṣe lè ran àwọn aláìní lọ́wọ́ àti láti ṣe ìtọ́jú fún aláìsàn lọ́nà tí ó dára, bí wọ́n ṣe lè ṣiṣẹ́ fún ọkàn tí kò tí ì yípadà. Àwọn ilé-ì wé gbọdọ̀ wà fún ẹ̀kọ́ ìlera, oúnjẹ sísè àti onírúurú ní ilé-ìwe ní ọ̀nà tí onígbàgbọ́ lè ṣè rànwọ́ iṣẹ́. Ìkọ́ni nìkan kò gbọdọ̀ wà ṣùgbọ́n iṣẹ́ pàtó ní abẹ́ àwọn olùkọ́ni tí ó lóye. Jẹ́ kí àwọn olùkọ darí ọ̀nà nínú ṣíṣiṣẹ́ láarin àwọn ènìyàn, àti àwọn yókù, ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú u wọn yóò lè kọ́ láti ara àpẹẹrẹ wọn. Àpẹẹrẹ kan sì níye lórí ju àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ lọ.—The Ministry of Healing, p. 149.IIO 59.3

    Larger font
    Smaller font
    Copy
    Print
    Contents